Ko si enikan ti o ni ife ti o tobi ju eyi lo, pe enikan fi emi re lele nitori awon ore re.@Johannu 15:13
Ralph Harrison
Charles C. Converse (1834-1918)

Joseph M. Scriven, 1855 (What a Friend We Have in Jesus); a ko mo eniti to seitumo.

Charles C. Converse, 1868 (🔊 pdf nwc).

Ralph Harrison
Joseph M. Scriven (1819-1886)

Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa!
Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si!
Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po,
Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re.

Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi?
A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa.
Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro,
Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa.

Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa?
Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa.
Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa.