Johannu kinni ori keta ese kinni.@1 John 3:1
aworan
John M. Driver (1858-1918)

John M. Driver, 1892 (Wonderful Story of Love); a ko mo eniti to seitumo (🔊 pdf nwc).

Itan iyanu t’ife! So fun mi lekan si
Itan iyanu tífe! Ti dun leti kikan
Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo
Elese, iwo ki yó gbo? Itan iyanu tífe!

Egbe

Iyanu! Iyanu!
Iyanu! Itan iyanu t’ife

Itan iyanu t’ife ! B’iwo tile sako
Itan iyanu t’ife! Sibe o npe loni
Lat’o oke kalfari, lati orisun didan ni
Lati ise-dale aiye; itan iyanu t’ife.

Egbe

Itan iyanu t’ife! Jesu ni isimi
Itan iyanu t’ife! Fun awon oloto
T’o simi n’ilu nla orun, Pel’awon to saju wa lo
Nwon nko orin ayo orun, itan iyanu t’ife.

Egbe